Káàbọ̀ sínú Oṣù tuntun, A sì kú ìsinmi òní.
Má ṣe gbàgbé pé ìdíje “TA NI Ọ̀JỌ̀GBỌ́N?” yóò bẹ̀rẹ̀ lóṣù yìí lórí gbogbo babaonigba. Àwọn Ẹ̀BÙN BÀǸTÀBANTA wà nílẹ̀ fún ọ láti jẹ”
Jẹ́ kí á mọ̀ bí inú rẹ bá dùn síi lábala àríwísí (Comment session).
Ẹ ṣeun!

